Yorùbá | Yoruba
- Kíni kí n bèèrè fún láti ríi pé mo ń gba àyẹ̀wò STD tó p'ójú owó?
- Ǹjẹ́ àwọn òògùn HIV tàbí PrEP máa ń dojú ìjà kọ òògùn ìwùwàsí ara àwọn tí wọ́n yípadà?
- Bíi ìgbà mélòó ni àwọn tó ní HIV máa ń ṣàyẹ̀wo iye kòkòrò tó wà nínu èjẹ wọn?
- Kíni Ipò Àìrí = Kò Lè Pín Kárí (U=U)?
- Ǹjẹ́ mo lè kó àrùn HIV láti fífi ẹnu ṣe ìbáṣepọ̀?
- Kíni àwọn oun tó máa ń fún mi ní ewu àti kó àrùn HIV?
- Kíni HIV?
- Ǹjẹ́ dókítà mi ní láti mọ̀ nípa irú ẹni tí mo ń bá lájọṣepọ̀ tàbí irú ẹni tí mo jẹ́ lọ́nà ìbáṣepọ̀?
- Ìgbà mélòó ló yẹ ká máa ṣe Àyẹ̀wò nípa HIV/STD?
- Níbo ni mo ti le ṣe àyẹ̀wò fún HIV/STD?
- Kí ni ìtumọ̀ kí nkan jẹ́ àìrí?