Fífi ẹnu ṣe ìbáṣepọ̀ kò lè fún ni ní HIV bíi ìbáṣepọ̀ ìdí tàbí ti ojú ara, ṣùgbọ́n kòkòrò àrùn yìí sì lè wọ ara rẹ láti ojú egbò tó ṣí sílẹ̀. A ti gbọ́ nípa irú àwọn ènìyàn tó kó àrùn HIV láti ẹnu, ṣùgbọ́n eléyìí kò wọ́pọ̀.
Fún àlàyé lẹ́kùnrẹ́rẹ́, ẹ wo iṣẹ́ yìí. (Ibi tí ẹ ti lè kà síi ní èdè òyìnbó)