Tí o bá wà ní U.S., lọ sí ibi oun èlò tí a fi ń wá ilé àyẹ̀wò CDC láti wá ilé àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ tí ó súnmọ́ ẹ̀ jù.
Tí́ o bá wà lẹ́yìn odi U.S., lọ sí ibi olùwárí HIV (Test Finder) AIDSMap.com (Ibi tí ẹ ti lè kà síi ní èdè òyìnbó)