Kìí ṣe gbogbo àwọn aláyìípadà ènìyàn ni wọ́n máa ń lo òògùn ìwùwàsí ara láti ṣe ìtọ́jú ìgbáyégbádùn ara wọn. Ṣùgbọ́n àwọn kan máa ń ṣe bẹ́ẹ̀. A kò tíì rí ìbáṣepọ̀ kankan láàrín àwọn ìlera fífi òògùn ìwùwàsí dípò ara wọn (hormone replacement therapy) àti PrEP.
Yẹ fídíò oníṣẹ̀jú kan yìí wò láti Greater Than AIDS fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. (Ibi tí ẹ ti lè kà síi ní èdè òyìnbó)