San Francisco AIDS Foundation gbàá nímọ́ràn pé àwọn ọ̀kùnrin tó bá ti ń ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú ọkùnrin mìíràn ní àkójọ pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ obìnrin, àti àwọn aláyìípadà obìnrin tí wọ́n bá ọkùnrin lò pọ̀ gbọdọ̀ ṣe àyẹ̀wò lóṣù mẹ́ta mẹ́ta. (Ibi tí ẹ ti lè kà síi ní èdè òyìnbó)